Èdè wa ni: Ẹ kọ́ àwọn ọmọ yín lédè Yorùbá kí wọ́n lè bọ́ nínú ìdè -Olùkọ́ èdè Ọ̀pádìjọ
A ṣe àbẹ̀wò sí ilé-ìwé sẹ́kọ́ńdìrì Ìtìrẹ́ Community ní ìlú Ìlasa láti fọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú olùkọ́ Yorùbá tó wa ni ilé-ìwé náà, Ọ̀túnba Hakeem Àkànní ọmọ Ọ̀pádìjọ tí wọ́n jẹ́ ọmọ Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè Àti Àṣà Yorùbá ilẹ̀ Nàìjíríà. A bá díẹ̀ nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn àtijọ́ sọ̀rọ̀ lórí ipa tí olùkọ́ wọn kó láyé wọn. Ọ̀túnba
Читать дальше...